Ìfòyà

Do-Do-Do Adjective Intermediate

Dictionary Definitions

1
Ìfòyà Fear (adj. )
Definition: (usually used predicatively, not attributively, be afraid) impressed with fear or apprehension; in fear.
Examples
Yorùbá: Kò sí ìfòyà fún ọmọ náà torí pé ó wá pẹ̀lú ìyá rẹ̀
English: There is no fear for the child because he was with his mother.
Synonyms
Ìbèrù; Ẹ̀rù