Febipa
Dictionary Definitions
1
Febipa
→
Starve
(v.
)
Definition: To suffer or die from lack of food and extreme hunger.
Examples
Yorùbá: Wọ́n febi pa ọmọ ajá náà ku nípa bí wọ́n ṣe jọ̀wọ́ rẹ̀ láti dà nìkan wà nílé.
English: They abandoned the puppy alone at the house thereby starving it to death.