Dọ́wẹ̀kẹ̀
Dictionary Definitions
1
Dọ́wẹ̀kẹ̀
→
Flirt
(v.
)
Definition: To show playful signs of attraction toward someone without any genuine romantic intent
Examples
Yorùbá: Àwọn olólùfẹ́ náà ń bára wọn dọ́wẹ̀kẹ̀ bí wọ́n ṣe ń rìn lọ́ ní pópónà.
English: The couple are flirting with one another as the walk through the street.