Àbùkù
Dictionary Definitions
1
Àbùkù
→
Disgrace; Defects; Abuse; Blemish; Failure
(n.
)
Definition: An imperfection or defect that spoils the appearance or quality of something.
Examples
Yorùbá: Olùdásílẹ̀ ohun èlò náà ránṣẹ́ pé kí wọ́n dá gbogbo àwọn ọjà tí ó ti kó jáde padà sí ilé iṣẹ̀ nítorí àwọn àbùkù tí ó jẹyọ nípa ọ̀nà tí wọ́n gbà ṣe wọ̀n, èyí tó sì fi àbààwọ́n tó hàn gbangba sílẹ̀ lára wọn.
English: The manufacturer recalled the product due to a faulty design that left a visible blemish on its surface.