Ọ̀pá
Dictionary Definitions
1
Ọ̀pá
→
Shaft; Rod
(n.
)
Definition: Long, slender rod or pole
Examples
Yorùbá: Àwọn ọkùnrin fúlàní a máa darí àwọn màálù wọn pẹ̀lú ọ̀pá kan ṣoṣo.
English: The fulani men herds their cattle with a single rod.