Ọ̀pọ̀lọpọ̀

[ɔ̀k͡pɔ̀lɔk͡pɔ̀] Do-Do-Re-Do Adjective Advanced

Dictionary Definitions

1
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Many (adj. )
Definition: Large number; abundance
Examples
Yorùbá: Ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn ló wà níbi ayẹyẹ ìgbéyàwó náà.
English: There were many people at the wedding ceremony.
Synonyms
Ọ̀pọ̀