Ìmúláradá

[ìmúláɾadá] Do-MI-MI-Re-MI Noun Advanced

Dictionary Definitions

1
Ìmúláradá Healing (n. )
Definition: Process of becoming healthy again
Examples
Yorùbá: Ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ènìyàn ló gba ìmúláradá níbi ìsọjí ìtagbangba náà.
English: Many people recieved their healing at the outdoor revival crusade.