Eyín

[ejí̃] Re-MI Noun Beginner

Dictionary Definitions

1
Eyín Egg; Teeth (n. )
Definition: Some hard, white structures in the mouth used for biting and chewing food.
Examples
Yorùbá: Ọmọ ìkókó náà ti hu eyín rẹ̀ pé bí wọ́n ṣe bíi
English: The newborn had a complete set of teeth at birth.