Hàn
Dictionary Definitions
1
Hàn
→
Visibility
(n.
)
Definition: State of being seen or noticeable
Examples
Yorùbá: Ojúlówó àwọ̀ aṣọ náà kò fi bẹ́ẹ̀ hàn nínú àwọn àwòrán fọ́tò 1950 yẹn.
English: The real colour of the cloth was not really visible in the 1920's photographs.
Antonyms