Alájọpín

[aláʤɔk͡pí̃] Re-MI-Re-MI Noun Advanced

Dictionary Definitions

1
Alájọpín Shareholder (n. )
Definition: One who owns shares of stock in a corporation.
Examples
Yorùbá: Àwọn alájọpín ilé iṣẹ́ náà gbìmọ̀ pọ̀ láti gba iṣẹ́ lọ́wọ́ adarí ilé iṣẹ́ náà.
English: The shareholders of the company conspired together to sack the ceo.
Synonyms
Onipindoje; Alábàákẹ́gbẹ́