Èpè
Dictionary Definitions
1
Èpè
→
Curse
(n.
)
Definition: Invocation of harm; malediction
Examples
Yorùbá: Wọ́n gbàgbọ́ pé àìrọ́mọbí rẹ̀ jẹ́ àtubọ̀tán èpè tí ìyá rẹ̀ ti ṣẹ́ fùn nígbà tí ó wà ní kékeré.
English: They believed that her barreness is as a result of the curse her mother placed on her when she was young.