Ajalèlókun

[aʤalèlókũ] Re-Re-Do-MI-Re Noun Advanced

Dictionary Definitions

1
Ajalèlókun Pirate (n. )
Definition: A criminal who plunders at sea; commonly attacking merchant vessels, though often pillaging port towns.
Examples
Yorùbá: Ó yẹ kó o ṣọ́ra nítorí àwọn ajalèlókun tó wà ní orílẹ̀-èdè somalia.
English: You should be cautious due to the somalian pirates.