Àtúbọ̀tán

[àtúbɔ̀tá̃] Do-MI-Do-MI Noun Advanced

Dictionary Definitions

1
Àtúbọ̀tán Outcome; Result; Fate (n. )
Definition: The outcome of somthing or an action
Examples
Yorùbá: Àtúbọ̀tán ìdánwò náà dára gan-an
English: The outcome of the exam was very good
Synonyms
Àbájáde