Èrò
Dictionary Definitions
2 meanings found1
Èrò
→
Thoughts; Intentions; Opinion
(n.
)
Definition: Mental ideas; plans
Examples
Yorùbá: Ó jókòó jẹ́jẹ́ ó sì ń gba èrò nípa bí yóó ṣe gbẹ̀san lára ọ̀rẹ́ tí ó dalẹ̀ rẹ̀.
English: She sat quietly and was thinking about how to plot her revenge against her frienfd who betrayed her.
2
Èrò
→
People; Crowd; Passenger
(n.
)
Definition: Human beings considered collectively or in groups
Examples
Yorùbá: Awakọ̀ ọkọ̀ akérò náà já gbogbo àwọn èrò tí ó kó sílẹ̀ láàrin ọ̀nà.
English: The bus driver dropped all the passengers half-way.
Synonyms